Ibuwole Si Agbo EsinIslam Ni Yoruba Titun. Lati Ojo Jum'ah 28th Osu Karun Odun 2010. Apa Ese Oju Agbo Wa Yi Yio Je Mimojuto Ati Mimo-Dogba Lati Owo Awon Akeko Sheikh Wa Sheikh Abu-Abdullah Adelabu Ti Nwon Wa Ni Islam Yi:
Omo-Iya Wa Arakunrin Hafiz Adesoka
Omo-Iya Wa Arabirin Madinah Aziz
Omo-Iya Wa Arakunrin Najim-ud-din Adisa
Omo Iya Wa Arakunrin Ismail Hamzah
Omo-Iya Wa Arabirin Mariam Abiola
Ekunrere alaiye Nipa Awon Asiko Eto Ti Wa Ni Ifiranse Si Awon Omo-Egbe Ti Nwon Fi Orukosile Ni Awqaf Africa, Fatih-ul-Fattah, Taqiah Sisters Ati Ni Ile-Eko Giga Ti Awqaf Bakanna.
Ojule Agbo EsinIslam Titun