www.esinislam.com
 
     
Search Results for: Yoruba Media
:: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin, Atoka, Iwe-Irohin ...

Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, ni nnkan bii aago merin oru ojo keeedogbon, osu kin-in-ni, odun yii, nisele naa waye ni ojule ketalelogun, laduugbo Abari, n'Iyana-Ipaja, niluu Eko, iyen nigba ti Grace gbimo-po pelu orekunrin re to n je Benjamin Otu lati pa oko re ti won jo wa lati Akwa Ibom pelu obe idana.

- Onka Yoruba - esinislam.com

Onka Yoruba Lati Ori Ookan De Egbeegberun Lona Egberun - Yoruba Numbers from 1 (One) to 1,000,000,000 (One Billion) Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):

EsinIslam Media - Onka Yoruba - Numbers In Yoruba: Figures ...

Onka Yoruba Lati Ori Ookan De Egbeegberun Lona Egberun - Yoruba Numbers from 1 (One) to 1,000,000,000 (One Billion) Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):

:: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin, Atoka, Iwe-Irohin ...

Iwadii Iwe Iroyin Yoruba fi han pe omo osu meje pere ni omobinrin toruko re n je Favour ohun, o si ku die ki Happiness ri i gbe sa lo kowo too te e. Ohun ti a ri gbo ni pe awon olopaa ayarasise (Rapid Response Squad) to n sise lagbegbe Eric Moore lo ri okunrin naa ti won si fura si irin ese re.

- Eru n Bawon Ara Mushin Nitori Oriyomi Ti Won Dajo Iku Fun ...

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe o pe ti Oriyomi ti maa n paayan, to si maa n mu un je, sugbon aago re to kun a-kun-wo-sile ni ko se mori bo nigba towo te e pe o gbemii ore re. Iwadii fi han pe odun 2013 lowo koko te e, iyen lojo kesan-an, osu kesan-an. Nigba ti won wo o de kootu majisreeti to wa l'Ebute-Meta, odaran yii jewo pe omo egbe okunkun Black ...

:: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin, Atoka, Iwe-Irohin ...

Ni orile-ede yii loni-in, ipo kerinla lomo Yoruba wa. A ko si nipo Aare, a o si nipo igbakeji, a o si nipo awon olori ile igbimo asofin mejeeji, bee lo je pe omo Yoruba ko si nipo olori awon adajo. Nibi toro ohun buru de, omo Yoruba ko ni olori awon osise ijoba.

- Owo Te Oladele To N Ta Ori Eeyan N'Ibadan :: EsinIslam ...

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, aajin oru lawon olopaa loo ka okunrin naa mole, boya oogun ifura to si n lo lo je ko mo pe won ti wa nitosi ni, tabi boya o gburoo awon agbofinro naa nigba ti won de enu ona ile e, ko si eni to ye, ohun to sa han sawon agbofinro ni pe won ko ba baba naa nile, jagunlabi ti ta poro ba ona eyinkule sa lo.

Pasito Oluso-agutan Femi Olayinka Tijo 'Christ Miracle' Fun ...

Lati Owo Akoroyin Olootu Pasito Oluso-agutan Femi Olayinka Tijo 'Christ Miracle' Fun Iyawo Omo Ijo e Loyun N'Ife Ile-ejo koko-koko to wa niluu Ilesa ni Ogbeni Olusola Onifade gbe iyawo re, Arabinrin Simbiatu, to fesun agbere kan lo, nibi to ti rawo ebe sadajo lati tu igbeyawo odun mewaa to wa laarin won ka.

- Odidi Odun Meta Loko Mi Fi Pa Mi Ti, Mi o Se Mo — Taiwo ...

Lati Owo Akoroyin Olootu Odidi Odun Meta Loko Mi Fi Pa Mi Ti, Mi o Se Mo — Taiwo Igbeyawo ogun odun kan lo ti wa ni bebe iforisanpon bayii pelu bi iyaale ile naa se n kunle, to n rababa nile-ejo koko-koko kan to wa ni Oke-Eda, niluu Akure, pe ki won ba oun fopin si ibasepo olodun gbooro to wa laarin oun atoko oun lori esun pe okunrin naa pa oun ti bii aso to ti gbo fun odidi odun meta.

- A Ko Gba Iwole Sibi Yi :: EsinIslam Yoruba Media Fun Iroyin ...

EsinIslam Media: A Ko Gba Iwole Sibi Yi Eyin N Gbiyan Lati Wo Apa Ibi Ti A Ko Fi Aaye Gba Wiwo Re. E Jowo E Ma Binu Si Eyi, Sibesibe A Se Apa Oju Alantakun EsinIslam Yi Ki O Wa Fun Awon Alufa-Agba Ati Awon Eni Esa Fun Ash-Shuraa (i.e. Ijo Igbimo) Ti Egbe Awqaf Ati Fun Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Tabi Ninu Egbe Olomobirin ...

Next Matches
 
 

www.esinislam.com