Gbagede Yoruba
 



O Tan! Wahala Egbe Afenifere N Po Si Lehin Ti Fasoranti Kowe Fipo Asaaju Sile
 
Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu Lati Owo Akoroyin Olootu

O Tan! Wahala Egbe Afenifere N Po Si Lehin Ti Fasoranti Kowe Fipo Asaaju Sile

Wahala sese bere ni lehin ti Asaaju egbe Afenifere, Alagba Reuben Fasoranti, ti kowe fipo e sile gege bii asaaju egbe naa. Lasiko to n soro nipa ohun to mu un gbe igbese ohun, baba eni ogorin odun naa so pe nitori irepo ti ko si ninu egbe naa mo lo je koun fipo ohun sile.

Gege bi o ti jeyo ninu leta ifiposile ti baba yii ko sawon agba egbe lo ti so pe ohun ibanuje lo je foun bi awon omo egbe ko se wa ni irepo, ti won ko si tele ilana ti Oloogbe Obafemi Awolowo la kale lati je ki isokan wa laarin awon omo Oodua. Baba yii so pe ohun ti ko bojumu to ni bi iyapa se wa ninu egbe Afenifere.

Alagba Fasoranti fi kun oro re pe kete ti ipo asaaju egbe naa bo soun lowo ni orisiirisii nnkan ti n sele nibe, ti enu awon omo egbe naa ko si ko. O ni opolopo igbese loun ti gbe lati je ki ilosiwaju ati irepo ba egbe yii, sugbon pabo ni gbogbo e ja si, tawon omo egbe naa ko si fenuko mo.

O so o di mimo pe gbogbo agbara oun ati gbogbo nnkan toun ni pata loun fi sin orile-ede oun, ipinle oun, egbe oselu oun, awon asaaju oun ati egbe Afenifere nile yii ati loke okun pelu ojo ori oun, eyi lo se se koko lati fipo asaaju egbe Afenifere sile fawon mi-in. O ni loooto loun ti fipo asaaju egbe yii sile, sugbon oun si faramo ohun ti egbe Afenifere panupo so lasiko ipade apero to koja yii.

Leyin iku Oloogbe Adekunle Ajasin nipo asaaju egbe Afenifere bo sowo Oloogbe Abraham Adesanya, nigba ti baba yii wa ni idubule aisan lo gbe ipo naa le Alagba Fasoranti lowo.

Asiko baba yii legbe naa fo si meji, tawon kan loo da egbe Afenifere Renewal Group sile.

 Posted By Ifiranse Eleyi Je Friday, April 29 @ 04:52:09 PDT Lati Owo MediaYorubaTeam



Comments 💬 التعليقات
 

For Your Membership Comments And Registered Debates Please, See Below Or Register Here :-: للحصول على تعليقات عضويتك و مناقشات الأعضاء انظر من فضلك أدناه أو سجّل هنا

Awọn ọna asopọ ti o jọmọ

· Die sii Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu
· Iroyin Nipasẹ MediaYorubaTeam


Ọpọlọpọ Itan Ka Nipa Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu:
Ojo Buruku, Esu Gbomimu L'ojo Ti Won Pariwo "Ole" Le Awolowo Lori


Iwọn Abala

Apapọ Dimegilio: 0
Awon Ibo Ni Oniyi: 0

Jọ̀wọ́ Gba Ẹ̀ẹ̀kejI ki o sI dIbo fun Abala YIi:

O tayọ
O dara pupọ
O dara
Deede
Buburu


Aṣayan


 Ọrẹ-itẹwe Ọrẹ-itẹwe





Akole Atoka Agbo-Oro

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu



"O Tan! Wahala Egbe Afenifere N Po Si Lehin Ti Fasoranti Kowe Fipo Asaaju Sile" | Buwolu wọle/Ṣẹda Eto Akọsilẹ | 0 Awon Alaiye


Awọn asọye jẹ Ohun ini nipasẹ Iwe ifiweranṣẹ. A Ko Lodidi Fun Akoonu wọn. Nibayi, A Pe Awọn oluka lati jabo Eyikeyi Abusive, Unsuitable And/tabi Islamophobic Content



Ko si awọn ọrọIwoye Ti o gba laaye Fun Aisinisi, Jọwọ Forukọsilẹ
 

Gbagede Yoruba
Akọọlẹ Tirẹ
Ojule Akọkọ  | Awọn Itan Yoruba  | Gbagede Yoruba  | Ifiranṣẹ Ara-ẹni  | Ọmọ-Ẹgbẹ Yoruba  | Koko Mẹwa  | Ẹka Abule  | Ifirohin-Ransẹ  | Iwadi  | Agbeyẹwo  | Ifimufilẹ  | Iwe Akọọlẹ  | Apoti Akọsilẹ  | Isopọ Ọpọnlujara  | Ẹgba Ayelujara  | Ipolongo Wa


Ẹsin Islam الدين الإسلامي Religion of Islam Addinin Musulunci Agama Islam Religión del Islam 伊斯兰教 Dini ya Kiislamu Религия Ислам Religião do Islã イスラム教 Esin Islam 이슬람의 종교 Portal African Muslim Website - Arabic English African Islamic Website For World News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Articles, Radio, Audio, Video, Quran, Hadith, TV Channels, Fatwas, Muslim News, Newspapers, Magazines Headlines, Forums, College, Schools, Universities, Mosques, Quranic, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Ramadan, Vidoes, Books, Fasting, PDFs On EsinIslam.Com And IslamAfrica.Com