Prev  

101. Surah Al-Qâri'ah سورة القارعة

  Next  



Ayah  101:1  الأية
    +/- -/+  
بِسْم ِ اللهِ الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ

Ayah  101:2  الأية
    +/- -/+  

Ayah  101:3  الأية
    +/- -/+  
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْقَارِعَةُ
Yoruba
 
Kí sì l'ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Àkókò ìjáyà?

Ayah  101:4  الأية
    +/- -/+  
يَوْمَ يَكُونُ النَّاسُ كَالْفَرَاشِ الْمَبْثُوثِ
Yoruba
 
(Òhun ni) ọjọ́ tí ènìyàn yó dà bí àfòpiná tí wọ́n fọ́nká síta,

Ayah  101:5  الأية
    +/- -/+  
وَتَكُونُ الْجِبَالُ كَالْعِهْنِ الْمَنفُوشِ
Yoruba
 
Àwọn àpáta yó sì dà bí ẹ̀gbọ̀n òwú tí wọ́n gbọ̀n dànù.

Ayah  101:6  الأية
    +/- -/+  
فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَازِينُهُ
Yoruba
 
Nítorí náà, ní ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá tẹ̀wọ̀n,

Ayah  101:7  الأية
    +/- -/+  
فَهُوَ فِي عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ
Yoruba
 
Ó sì máa wà nínú ìṣẹ̀mí tó máa yọ́nú sí.

Ayah  101:8  الأية
    +/- -/+  
وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَازِينُهُ
Yoruba
 
Ní ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá sì fúyẹ́,

Ayah  101:9  الأية
    +/- -/+  

Ayah  101:10  الأية
    +/- -/+  
وَمَا أَدْرَاكَ مَا هِيَهْ
Yoruba
 
Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ bẹ́ẹ̀?

Ayah  101:11  الأية
    +/- -/+  
 


© EsinIslam.Com Designed & produced by The Awqaf London. Please pray for us